Christian Devotional ADs

Download Shola Allyson – Akosile

Artist: Shola Allyson

Track Title: Akosile

Genre: Gospel; Christian

Recorded: 2003

Album Name: Eji Owuro Soundtrack (7 Tracks)

Country: Nigeria

Category: Gospel Songs

Shola Allyson, a highly respected Yoruba gospel singer, released the impressive track “Akosile” in 2003 as the fourth song off her debut studio album, “Eji Owuro.” This album brought her fame in the Nigerian gospel industry and includes seven carefully crafted tracks.

She came into limelight with the hit album “Eji Owuro.” Shola Allyson, whose full name is Sola Allyson-Obaniyi, is a well-known name in the Nigerian music industry.

Download Latest Songs / Music, Videos & Albums/EPs here On JustGospel.

Listen and share this amazing song for free and stay happy.

DOWNLOAD MP3

Video: Shola Allyson – Akosile

Akosile Lyrics by Shola Allyson

Akosile ti duro akosile o le tase oun toluwa base eda kan kole yi
Pada ibi ori n gbe ni lo kese ma si ni lona oun to wun eleduwa lo le
Yan fun wa atibi atire ton sele lala eda kole ye e e akosile ti duro
Kole tase o o o, ayanmo eda ti duro kirakita o dola laye gbogbo eto
Olorun kose ni tole ba tun to gbogbowa lan sare kiri pe ka lola ka
Jeniyan sugbon ta lole mo ibi ori dawun si atibi atire ton sele lala
Eda kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se,
Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye
Mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Kadara eda ti duro ife eleda o le ye lai ona ti o ba wun olorun oun
Lole mu ese eda to ori e o dade ofe jo ba o wa n ba yanmo jijakadi
Boti wun e ni to dale lose n foyin si atibi atire ton sele lala eda
Kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o,
Eniyan ma yo ra leun koya gba folorun lo to womo meji tabi lojo kan
Ayanmo ototo loyan onise ika n sorire onise re wan to si Awa bi
Olorun lere bo se je boti wun oluwa lon soro kose ni tole da lejo
Akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se o baba
Koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.
Oro olorun ede ni ileri re ko le ye lai oun ti oluwa ba pinu ife ota
Kan o le pada oti pinu pe ki sorire pe ki lola ki n jeniyan oun
Toluwa ba ko ko seni to le yi bo ti wun oluwa lon soro oun lo layo
Ati ola akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se,
Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire
Ni kofimi da, wa ba mi se mo bebe,
Iwo lo ran mi wa ba mi se kaye mi
Ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.

Translate to English