Download Shola Allyson – Ife A Dale

Artist: Shola Allyson

Track Title: Ife A Dale

Genre: Gospel; Christian

Recorded: 2021

Album Name: Isodotun (9 Tracks)

Country: Nigeria

Category: Gospel Songs

Gospel singer Shola Allyson has included “Ife A D’ale” as the third track on her successful album “Isodotun”. The song, which has been widely praised by fans, is a tribute to exaltation.

Released in 2021, “Isodotun” is a collection of nine captivating tracks, designed to appeal to gospel music enthusiasts globally. Shola Allyson’s talents extend beyond gospel music, she also has a reputation for creating soundtracks for Yoruba films.

Download Latest Songs / Music, Videos & Albums/EPs here On JustGospel.

Listen and share this amazing song for free and stay happy.

DOWNLOAD MP3

Video: Shola Allyson – Ife A D’ale

Ife A D’ale Lyrics by Shola Allyson

Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale o
Ife yi a d’ale o, ire
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife wa a d’ale, ire
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife yi a d’ale o, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife yi a d’ale o, ire
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife yi a d’ale o, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ibukun ba s’ori wa
Amin o
Ibukun ba s’ori wa
Ibukun ba s’ori wa o
Iranwo a wa fun wa
Amin o
Iranwo a wa fun wa
Iranwo a wa fun wa o
Idimu a di wa mu o
Amin o
Idimu a di wa mu o
Idimu a di wa mu oo
Ike ati ige a maa ba wa lo
Ike ati ige a maa ba wa lo ooo
Ike ati ige a maa ba wa lo
Ike ati ige a maa ba wa lo o
Ere a po fun wa
Amin o
Ere a po fun wa
Ere a po fun wa o
Imole a tan fun wa
Amin o
Imole a tan fun wa
Imole a tan fun wa o
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife wa a d’ale o, ire
Ire lat’ oke wa
Ibukun ti kii si lo
Ire ti o se e gbon danu
Ife wa a d’ale o, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale ooo
Ife wa a d’ale
Ife wa a d’ale, ire